Grateful

Grateful 歌词

年份2014
流派Pop
时长6:59
原文语言英语
浏览量471
歌词坐标

原文歌词

EN
暂时没有翻译,当前显示原文歌词。
18
Era ile, era ile Won yin baba l'oke Yanrin okun, yanrin okun Won n yin baba l'oke Eranko ile, eranko igbo Won n yin baba l'oke Awon alaini, awon tan ti ni Won yin baba l'oke Ko se igbati nkan ba se yan Ko to mo pe baba n be l'oke Ko se igbati nkan ba se yan Ko to mo pe looto o n be l'oke You don't have to wait till you feel the pain You can start right now It's not too late It's not too late, to be grateful Era ile, era ile, Won yin baba l'oke Yanrin okun, yanrin okun Won yin baba l'oke Pe mo wa laye, mo wa laye Gbogbo n ti mo ni, ma fin yi o l'ogo Believe this world a better place Ko se igbati nkan ba se yan Ko to mo pe baba n be l'oke Ko se igbati nkan ba se yan Ko to mo pe looto o n be l'oke You don't have to wait till you feel the pain You can start right now It's not too late It's not too late, to be grateful Wo mi, bi mo se n f'ope ye baba Da di da dada Da di da dudu Da di da dada Da di da dudu It's not too late