Aisha

Aisha 歌词

年份2010
流派Soul
原文语言YO
浏览量37
歌词坐标

原文歌词

YO
暂时没有翻译,当前显示原文歌词。
18
Aisha, omidan ọla, ma sunkun Aye rẹ, o wa niwaju ẹ Onikaluku wa, gbogbo wa ni ododo Aisha, wahala ni aye Gbadun ni aye, ọjọjumọ ni o Oju ọjọ k'a maa dupẹ o Ọmọde maa sunkun, aye yii o daa Fi ogun silẹ, ma lọ Aisha, omidan ọla, ma sunkun Aye rẹ, o wa niwaju ẹ, ọmọde Onikaluku wa ma jẹ ẹjọ ninu aye Onikaluku yoo duro fun ẹsan ọmọ Aisha, ma lọ Aisha, omidan ọla Ọmọde, wa k'a lọ Omọde, onikaluku wa l'ahun wa ododo Aisha Aisha