OBT (One Big Transaction) (feat. Bhadboi OML)

Letra de OBT (One Big Transaction) (feat. Bhadboi OML)

Idioma originalPCM
Visualizações31
Coordenadas da letra

Letra original

PCM
A tradução ainda não está disponível. Exibindo a letra original.
18
Oh, baba yẹ, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi One big transaction, tó ma change story mi Malaika tó n gbé're, jọ wá gbé'rẹ s'odo mi Oh, babá ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (ob—, Obah) Oh my maye, ma ma k'ohùn mi (wah dem a say?) One big transaction, to ma change story mi Malaika tó n pín'rẹ́, jọ̀wọ́ pín'rẹ d'odọ̀ mi Wọn ni Naija ṣI ma dùn, but you dey America E go better la ti n gbó la t'aye Abacha Owo t'ọmọde bá kọ́ rí, á fi jẹ akara If I see first money, mo ma sá lọ Canada Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (shoday, kí lo dé?) Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (hum) One big transaction, to ma change story mi Malaika tó n pín'rẹ́, jọ̀wọ́ pin're d'odo mi (oh, babá yè) Oh, babá ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (dáhùn sọ̀rọ̀ mi) Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi) One big transaction, tó ma change story mi (ehn) Malaika tó n pínrẹ́, jọ̀wọ́ pin're d'odo mi (oh, babá yè) Ibí e ní gbégbé kò ma gbé, ibè ló ma gbé (ibè ló má gbé) Ọjà to ni gbégbé kò ma gbé, gbogbo ẹ ló ma gbé (gbogbo ẹ ló ma gbé) Purple Haze ninu brown rizzler, high me my canister Oh my maye ye-ye, wa gbé mi trabaye, ye-ye-ye Ayy, it's going, it's going, olomi kò ní s'oṣI, kò ní s'ofo They're trolling their father, I'm stoning pẹ̀lú kpoli, pẹ̀lú coco Kò sí problem, kò sí yawa, kò sí story, kò sí glory, ọmọ ologo Ah, dorime fún ọmọ ọpẹ́ (dorime fún ọmọ ọpẹ́) Ọmọ oro mi wá pẹ (ọmọ oro mi wá pẹ) Oh, baba ye Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi) Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi) One big transaction, tó ma change story mi (ehn) Malaika tó n pín're, jọ̀wọ́ pín're d'odo mi Oh, baba ye Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (dáhùn, dáhùn, dáhùn, dáhùn sọ̀rọ̀ mi) Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi) One big transaction, to ma change story mi (ehn) Malaika tó n gbé'rẹ, jọ wá gbé'rẹ d'odo mi