Feel Good

Feel Good 가사

장르Afrobeats
원문 언어YO
조회수354
가사 좌표

원문 가사

YO
번역이 아직 없습니다. 원문 가사를 표시합니다.
18
Ìmọlẹ Plenty enemy (Mohbad) Wey dey follow me Májẹ k'ọ mú mí Even if na dying minute Èmi ọmọ ghetto Mo tí d'aji lo motor (mo tí d'aji lo motor) My grace na auto, automatic Wọn fẹ bami ya photo (photo) Èmi tí gbéra (on God) Láti 4:30 (on God) Wọn lé, wọn bà tí (on God) Wọn mu, wọn filẹ (on God) I drip on, jẹ k'onduro (on pause) Ìmọlẹ (on God) O wa'lẹ (on God) (On God) Ahn, when I dey Ikorodu, sapa mu mi Mo má ronú Mo má sunkún (mo má sunkún) Ehn, I don work tire I don pray tire I don go Mountain of Fire, ah I know there is a day All my pains will go away 'Til then, I'll party away I know there is a day All my pains will go away 'Til then, I smoke it away I feel good, pa, ran-ran, pa, ran-ran ỌMọ ìyá mí, má lọ ronú o, ko pa, ran-ran, pa, ran-ran I feel good (pa, ran-ran) Èmi ọmọ ghetto (emi ọmọ ghetto) Mo tí d'aji lo motor (mo ma tí d'aji lo motor) My grace na auto, automatic Wọn fẹ bami ya photo (photo) Èmi tí gbéra (on God) Láti 4: 30 (on God) Wọn lé, wọn bà tí (on God) Wọn mu, wọn filẹ (wọn mu, wọn filẹ) (on God) I drip on, jẹ k'onduro (on pause) Ìmọlẹ (on God) O wa'lẹ (on God) (On God) Ìmọlẹ, o wa'lẹ B'oṣe ń múlẹ, lọ ṣe ń jẹ Lát'ayé tipẹ-tipẹ Ìmọlẹ, o wa'lẹ B'oṣe ń múlẹ', lọ ṣe ń jẹ Lát'ayé tipẹ-tipẹ Plenty enemy Wey dey follow me Májẹ kọ mumi (Ìmọlẹ) (Timi Jay on the track)