Oxalá

Oxalá 가사

연도2025
장르Pop
원문 언어YO
조회수1.1K
가사 좌표

원문 가사

YO
번역이 아직 없습니다. 원문 가사를 표시합니다.
18
Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà Elémoṣọ̀ bàbá Ológun Ajagunà gbà àwọ̀ Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà Elémoṣọ̀ bàbá Ológun Ajagunà gbà àwọ̀ Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà Elémoṣọ̀ bàbá Ológun Ajagunà gbà àwọ̀ Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà Elémoṣọ̀ bàbá Ológun Ajagunà gbà àwọ̀ Ò fúrùrú lóòréré o Àìláà Bàbá kényènyè ní Ejìgbò Ilé Ìfọ̀n mo ti wá, Bàbá Ejìgbò rere, mo júbà ó Olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe Ò fúrùrú lóòréré o Àìláà Bàbá kényènyè ní Ejìgbò Ilé Ìfọ̀n mo ti wá, Bàbá Ejìgbò rere, mo júbà ó Olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe Ò fúrùrú lóòréré o Àìláà Bàbá kényènyè ní Ejìgbò Ilé Ìfọ̀n mo ti wá, Bàbá Ejìgbò rere, mo júbà ó Olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe Ò fúrùrú lóòréré o Àìláà Bàbá kényènyè ní Ejìgbò Ilé Ìfọ̀n mo ti wá, Bàbá Ejìgbò rere, mo júbà ó Olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe Àṣẹ, Bàbá Ọlọrun orílẹ̀ Ọṣàlá bèsí fún ọ Ẹ̀bẹ̀ Bàbá Oníṣà wúrè, àwọn l’àṣẹ Onisá wure oberi omã Oníṣà wúrè Àwọn l’àṣẹ, Bàbá Onisá wure oberi omã Oníṣà wúrè, àwọn l’àṣẹ Onisá wure oberi omã Oníṣà wúrè Àwọn l’àṣẹ, Bàbá Onisá wure oberi omã Oníṣà wúrè, àwọn l’àṣẹ Onisá wure oberi omã Oníṣà wúrè Àwọn l’àṣẹ, Bàbá Onisá wure oberi omã O navio negreiro não foi Um encontro marcado A gente resiste Por não ser cultura, no nosso país Aquilo que deveria ter sido Então, eu refaço esse caminho novamente E, através desse novo navio Encontra-se, na Bahia E a gente, enfim, pode viver A cultura africana no país chamado Brasil