Military

Military 가사

장르Pop
원문 언어YO
조회수55
가사 좌표

원문 가사

YO
번역이 아직 없습니다. 원문 가사를 표시합니다.
18
Uh Àwọn ló ń l'ẹ́nu Wọ́n kò ń máa sọ lò Ti ò bá ti affẹ́ct bank mi, kó máa sọ̀rọ̀ Making money, mo wà focused Military régime, show love La mèdàl ló ń ọmọ tó ń sọ Ó kan máa sáré, sáré, sáré, o ò le bá a bó ti lọ Èmi kò ní Ọlọ́run ni, Ọlọ́run ló dá a mi Òyìnbó kòrò l'ẹ́nu mi For my set, who get money pass me? Kò má sì Èmi kàn like low-key Achievement all over the world, wọ́n mọ̀ Stubborn, you fit do am? Ó yá, go front Make I stop, make I chill I fit dey go from now till early mó̩-mó̩ Ọmọ Ọlọ́run Mi ò gbọ́dọ̀ máa sọ̀rọ̀ too much Pause if you must, but don't stop Shout out Olamide Badoo Ìdàn Mo lè drop album l'ọ̀lá ti inú bá bì mi Zero tracklist, mo lè gbé wọn sáré ni Mo lè ní kí wọ́n lọ gba wọ́n lẹ́ti ni, but máa stop it torí pé mo ṣiṣẹ́ dé bí ni Talk your shit, mo mọ̀ pé o máa ń kó bà mi Ọmọ, fuck that shit, kúrò níbí ni Ṣé àgídí ni? Bọ̀bọ̀, bọ̀bọ̀, má gb'ọ̀wọ́ mi Alákọ̀bá jìná s'ọ̀dọ̀ mi For my set, who get money pass me? Kò má sì Èmi kàn like low-key Achievement all over the world, wọ́n mọ̀ Stubborn, you fit do am? Ó yá, go front Make I stop, make I chill I fit dey go from now till early mó̩-mó̩ Ọmọ Ọlọ́run Mi ò gbọ́dọ̀ máa sọ̀rọ̀ too much Pause if you must, but don't stop