Bahia

Bahia 歌詞

アルバムBlack Ivory Soul
2002
ジャンルSoul
時間3:34
原文言語YO
閲覧数624
歌詞座標

原文歌詞

YO
翻訳はまだありません。原文を表示しています。
18
Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè Didan ni ilé ti bahia Ti émin mon wa, ri yin lénin o Bahia, Bahia, Bahia Bahia, Bahia, Bahia Bahia, Bahia, Bahia Bahia, Bahia, Bahia (Ile aye) Ilé ti babawa jina, awa fè lolé (ile aye) Bahia ilu ti awa leni, opè gan si ilé (ile aye) Ogun ti awon agbalagba, se kalè fun wa o (ile aye) Logbé wa lo si Bahia, gbé gbogbowa po Bahia, Bahia, Bahia (oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia (oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia (oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia (oré ifé ayé yilé) (Ile aye) ojo ipadé wa m′bowa o, ti ale rira wa (ile aye) Ewa ka mura fojo yen ninu oyaya (ile aye) Oluwa fun wa niyé o, ejè ka du kpè (ile aye) Bahia pa gbogbowa po, iréti wa lona Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé Aburo, ibi kan ni wa o kamura si ifè Didan ni ilé ti bahia Ti émi mu wa, ri yin léni o (Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia (Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia (Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia (Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia Hmm, aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé (Bahia, Bahia, Bahia) Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè (Bahia, Bahia, Bahia) Didan ni ilé ti bahia ti émi mon wa, ri yin léni o (Bahia, Bahia, Bahia) (Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia (Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia (Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia (Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia Oré ifé ayé yilé