गीत निर्देशांक
YOमूल बोल
अनुवाद अभी उपलब्ध नहीं है। मूल बोल दिखाए जा रहे हैं।
Ọdẹ ko mọ ẹ̀ rọ̀ ọdẹ
Ọdẹ ko mọ ẹ̀ rọ̀ ọdẹ
Ọdẹ arère, ọdẹ ko mọ è rọ̀ ọdẹ, ni má yọ
Ọdẹ kọ mọ è rọ̀ ọdẹ, oníyè
Ọdẹ ko mọ ẹ̀ rọ̀ ọdẹ
Ọdẹ ko mọ ẹ̀ rọ̀ ọdẹ
Ọdẹ arère, ọdẹ ko mọ è rọ̀ ọdẹ, ni má yọ
Ọdẹ kọ mọ è rọ̀ ọdẹ, oníyè
Ọdẹ ko mọ ẹ̀ rọ̀ ọdẹ
Ọdẹ ko mọ ẹ̀ rọ̀ ọdẹ
Ọdẹ arère, ọdẹ ko mọ è rọ̀ ọdẹ, ni má yọ
Ọdẹ kọ mọ è rọ̀ ọdẹ, oníyè
Ọdẹ ko mọ ẹ̀ rọ̀ ọdẹ
Ọdẹ ko mọ ẹ̀ rọ̀ ọdẹ
Ọdẹ arère, ọdẹ ko mọ è rọ̀ ọdẹ, ni má yọ
Ọdẹ kọ mọ è rọ̀ ọdẹ, oníyè
Àwa ní sà Ọdẹ l'óko
Ẹ ń Ọfà a pa ẹran
Ọdẹ nsé ewé Ọdẹ l'óko
Ẹ ń Ọfà ki o kílé
E ara ayé
Ọdẹ arère òkè
Ẹ Òrìṣà le
Ẹ ń Ọfà a pa ẹran
Àwa ní sà Ọdẹ l'óko
Ẹ ń Ọfà a pa ẹran
Ọdẹ nsé ewé Ọdẹ l'óko
Ẹ ń Ọfà ki o kílé
E ara ayé
Ọdẹ arère òkè
Ẹ Òrìṣà le
Ẹ ń Ọfà a pa ẹran
Àwa ní sà Ọdẹ l'óko
Ẹ ń Ọfà a pa ẹran
Ọdẹ nsé ewé Ọdẹ l'óko
Ẹ ń Ọfà ki o kílé
E ara ayé
Ọdẹ arère òkè
Ẹ Òrìṣà le
Ẹ ń Ọfà a pa ẹran
Àwa ní sà Ọdẹ l'óko
Ẹ ń Ọfà a pa ẹran
Ọdẹ nsé ewé Ọdẹ l'óko
Ẹ ń Ọfà ki o kílé
A ko ké Ọdẹ
Òkè a ko ké Ọdẹ òkè
A ko ké Ọdẹ
Òkè a ko ké Ọdẹ òkè
A ko ké Ọdẹ
Òkè a ko ké Ọdẹ òkè
A ko ké Ọdẹ
Òkè a ko ké Ọdẹ òkè
A ko ké Ọdẹ
Òkè a ko ké Ọdẹ òkè
A ko ké Ọdẹ
Òkè a ko ké Ọdẹ òkè
A ko ké Ọdẹ






