Guoguo

Guoguo के बोल

शैलीAfrobeats
मूल भाषाYO
व्यूज़4
गीत निर्देशांक

मूल बोल

YO
अनुवाद अभी उपलब्ध नहीं है। मूल बोल दिखाए जा रहे हैं।
18
Bí 'gbà bà mí dùn Òun gbogbo a dá bí ere Gbogbo àyé a má yìn o Wọn a má pọn ẹ le l'ọtun, l'ósì o Bí 'gbà bà yi pere Gbogbo ilé a wá pa lọ-lọ Wọn a má kí ní l'atọọkàn, woah Ọwọ èpò, òun ní wón ń bá ní là o Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná) K'alẹ, kò lé dùn Là ṣé ń jí l'ówúrò s'ìṣẹ Ẹní àyé kàn kó lo jẹjẹ Kà má fí t'ẹní p'ọlá o Kò s'òun ta o rí-rí A tí r'ọmọ aládé tó ń d'ẹrú A dẹ tí r'ẹní tó ń ro pín, tó ń d'ọlọrọ Kà má f'aigbọ'n jìn s'ọ̀gbun (ọ̀gbun) Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná) Ilé wúràa má d áhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná) Ṣé bí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná) Ohh, ilé wúrà a má dáhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná) Ohh, ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná) Ilé wúrà Owó ò hùn kò ra tí 'gbẹ̀yìn Mo rí o ná Ilé wúrà Owó ò hùn kò rà tí 'gbẹ̀yìn Mo rí o ná