Beriwon

Beriwon के बोल

शैलीAfrobeats
मूल भाषाYO
व्यूज़3
गीत निर्देशांक

मूल बोल

YO
अनुवाद अभी उपलब्ध नहीं है। मूल बोल दिखाए जा रहे हैं।
18
Gbogbo àwọn tọ ní fẹ eto ilu Gbogbo àwọn tọ n pero po le da Gbogbo awon abaniṣe k'ọla k'ole dun Gbogbo awon ọlọwọ atunṣe o Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn) Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) Asiko ti to Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ Ẹ jẹ a gbáradi Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) Asiko ti to, oh-oh Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán Ẹgbẹ a tuni to Gbogbo àwọn ìyá ọlọwọ itọju (ah-ah-ah-ah) Gbogbo agba ọlọgbọn atọni s'ọna Gbogbo awọn ti o fẹ ki're ko sọnu (ah-ah-ah-ah) Gbogbo awọn ọdọ akíkanjú ẹni ire Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn) Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) Asiko ti to Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ Ẹ jẹ a gbáradi Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) Asiko ti to, oh-oh Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán Ẹgbẹ a tuni to Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn) Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) Asiko ti to Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ Ẹ jẹ a gbáradi Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) Asiko ti to, oh-oh Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán Ẹgbẹ a tuni to Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn) Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) Asiko ti to Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ Ẹ jẹ a gbáradi Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ) Asiko ti to, oh-oh Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán Ẹgbẹ a tuni to