Kílẹ̀nwò

Letra de Kílẹ̀nwò

GéneroAfrobeats
Idioma originalYO
Vistas4
Coordenadas de la letra

Letra original

YO
La traducción todavía no está disponible. Mostramos la letra original.
18
Oponu ọmọ na fi ṣe'aṣọna Dadandidin, afọfun ti o l'ero miran A fi ka ti jẹun gbangba, ka ti kọ'le gagara Ka ṣíṣẹ ara, ka ma wuga korofo Baba, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?) Yeye, ki lẹ n wo? (Omi kọ ja afara) Ẹgbọn, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?) Ọrẹ, ki lẹ n wo o? (Ori gongo orile) Oponu ọmọ na fi ṣ'atọna Akotileta ti o l'ero miran Aa fi ka ti l'owo, ka ti k'ọrọ jọ Ka f'eru gba 'bukun, Ìgbìmọ irọ Aagbagba, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?) Ẹyin ọdọ, ki lẹ n wo o? (Ile ma n dahòrò) Ah, ẹgbọn, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?) Ọrẹ, ki lẹ n wo o? (Ìlú ma n daṣálẹ) Oponu ọmọ t'an fi ṣ'olori ni'lu olopurọ Ko le ya ni lẹnu B'oju o ba ti wọn o, oju n t'ẹnire T'ori ọmọ to wọ lọja, ṣebí iyẹn lo ma n dun ni Ahh, baba, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?) Yeye, ki lẹ n wo? (Omi kọ ja afara) Ẹ'gbọn, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?) Ẹyin ọrẹ, ki lẹ n wo o? (Ori gongo orile) Ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?) Ki lẹ n wo o? Ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?) Ki lẹ n wo o? Agbagba, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?) Ki lẹ n wo o? Ẹyin ọdọ, ki lẹ n wo o? (Ki lẹ n wo o?) Ki lẹ n wo o? Ọrẹ, ki lẹ n wo o? (Ki lẹ n wo o?) Ki lẹ n wo o?